Quantcast
Channel: OnIslam Africa
Viewing all articles
Browse latest Browse all 474

Owun Ti Elesin Miran So Nipa Muhammad (Apakeji)

$
0
0

::jseblod::onislam_article::/jseblod::
::onislamarticleaction::::/onislamarticleaction::
::artpretitle:: ::/artpretitle::
::artsubtitle::Irving:Olusedeede ni Muhammad::/artsubtitle::
::artseries:: ::/artseries::
::artlead::Ti Muhammad ba nba eniyan se , o ma nse dogbandogba. Pelu deedee ni o fi nwuwa si ore ati adeji, olowo ati talaka, alagbara ati ole. Idi niyii ti awon eniyan fi feran re nitori bi o se nfawon mora ti o si fi ara bale gbo owun ti won fe so.::/artlead::
::artepigraph:: ::/artepigraph::
::artbody::

"Oniwapele ni,bakanna ni o ma nse iwontuwonsi pelu asaje nibi jije mimu re.Ko wa iyi tabi ogo kan fun ara re tabi ki  ofi ara se eso, Ko si ninu eni to nse igberaga lawujo.Aiwo aso gogowu re kin se ti aini laari.

Ti Muhammad ba nba eniyan se , o ma nse dogbandogba. Pelu deedee ni o fi nwuwa si ore ati adeji, olowo ati talaka, alagbara ati ole. Idi niyii ti awon eniyan fi feran re nitori bi o se nfawon mora ti o si fi ara bale gbo owun ti won fe so.

Gbogbo ogun ti o bori ko so di alaibikita tabi onigberaga, sebi iba gbe aso igberaga yii wo ti o ba je nitori inotiaraeni nikan ati iyi lo se jagun. Nigba ti o di alagbara ati olori , iwa re ko yato si asiko ti ko ti di ilumonka. Nigba ti o di Okansoso Ajanaku ti mi igbo kijikiji, ki nfe ki o de ibi kan , ki awon eniyan si paroro tabi ki won maa juba re. Ti o ba nfe ki owun joba agbaye, ko gbero ju ki esin Olorun Joba lokan awon eniyan lo; ti a ba wo akoso ilu ti o bo si owo re, a o ri wipe ko lo lati fi se karimi, bee sini ko gbe igbese lati jogun ipo yii fun awon ebi re."

A mu ayoka yii lati inu iwe:

"Life of Mahomet", London, 1889, oju ewe 192-3, 199

Washington Irving (1783-1859) je eni ti o gbajumo gege bi Akoko Ojogbon Onimo ile Amerika.

::/artbody::
::artendnote:: ::/artendnote::
::artfootnote:: ::/artfootnote::
::artmainimage::oimedia/onislamen/images/mainimages/Kini-Elesin-Miran-So-Nipa-Anabi-Muhammad-Apakeji.jpg::/artmainimage::
::artcaption:: ::/artcaption::
::artalt:: ::/artalt::
::artauthor:: ::/artauthor::
::artboximage::::/artboximage::
::artinterviewer:: ::/artinterviewer::
::artcompiler:: ::/artcompiler::
::artreviewer:: ::/artreviewer::
::arttranslator:: ::/arttranslator::
::artsource:: ::/artsource::
::artreference:: ::/artreference::
::artlink1:: ::/artlink1::
::artlinkurl1:: ::/artlinkurl1::
::artlink2:: ::/artlink2::
::artlinkurl2:: ::/artlinkurl2::
::artlink3:: ::/artlink3::
::artlinkurl3:: ::/artlinkurl3::
::artlink4:: ::/artlink4::
::artlinkurl4:: ::/artlinkurl4::
::artlink5:: ::/artlink5::
::artlinkurl5:: ::/artlinkurl5::
::button_submit::::/button_submit::
::jseblodend::::/jseblodend::

Viewing all articles
Browse latest Browse all 474

Trending Articles