::jseblod::onislam_article::/jseblod::
::onislamarticleaction::::/onislamarticleaction::
::artpretitle:: ::/artpretitle::
::artsubtitle:: ::/artsubtitle::
::artseries:: ::/artseries::
::artlead::Gbogbo Musulumi aye pata gbodo tara sasa lati ran awon omo iya wa lowo ni orileede CAR lori iwa ifiya jeni, ipakupa ati igbiyanju lati pa won re kuro ni awujo. Gbogbo igbese ti o ba ye ni ki a gbe lati fi opin si iwa ibaje yii, iranlowo gbodo yara de odo won lati mu inira kuro ninu oro won.::/artlead::
::artepigraph:: ::/artepigraph::
::artbody::
Ibeere:
As-salamu `alayum. A ti nfi eti gbo tipe nipa igbiyanju lati pa oripa awon Musulumi re ni orileede Central Africa Republic, kini ojuse Musulumi si iru isele bayii?
Idahun:
Wa `alaykum as-salamu wa rahmatullahi wa barakatuh.
Ni Oruko Oloun Oba Ajoke Aiye Oba Asake Orun.
Ike ati ige ki o ma baa Ojise Olohun Anabi Muhammad.
Adupe lowo omo iya wa fun ibeere yii, a be Olohun ki o ran Musulumi lowo nibikibi ti iya ba ti nje won.
Gbogbo Musulumi aye pata gbodo tara sasa lati ran awon omo iya wa lowo ni orileede CAR lori iwa ifiya jeni, ipakupa ati igbiyanju lati pa won re kuro ni awujo.
Gbogbo igbese ti o ba ye ni ki a gbe lati fi opin si iwa ibaje yii, iranlowo gbodo yara de odo won lati mu inira kuro ninu oro won.
Read Also: |
Fifi iya je eniyan ati pipa awujo kan re je iwa odanran ti o nkoju awon Musulumi orileede CAR, gbogbo aye gbodo dide lati fi opin si iwa yii.
Oranyan ni fun gbogbo Musulumi gege bi alaanu eniyan ati bi Esin Islamu se pawa lase lati dide iranlowo si awon omo iya wa nibikibi ti iya ba ti nje won.
Bakana, adua se pataki fun won, gbogbo irun oranyan kookan ti a ba nkii ki a ri wipe a nse akanse ibe Olohun fun won.
Gbogbo awon asiko ti adua ma nyara gba nibe ki a ri wipe a nso fun Olohun ki o bawa fi opin si inira yii.
Siwaju si, gbogbo ero ibanisoro igbalode ni o ye ki a maa lo lati fi ma ba ara wa soro lori isele yii ati lati fi ehonu wa han si gbogbo aye, boya Olohun leni ki a ri ona abayo lati ibe.
Gbogbo owun ti Musulumi kookan ba ni lagbara ki o fi sowo si awon omo iya wa, bii aso wiwo, ounje, inkan mimu, owo ati beebelo. Ki a si ri wipe awon igbimo ti oni ooto ati ododo ni a fi awon inkan won yii ran.
Gbogbo ijoba orileede Musulumi gbodo sa gbogbo ipa won lati dekun iwa obileje ti o nsele si awon Musulumi CAR.
Ni afikun si oro yii, Ogbeni Esam Harira, Oluwadi ofin Islamu ati akowe pataki ni eka idajo Islamu, ile ise OnIslam.net, so wipe:
Oranyan ni fun Musulumi kookan, ijoba, egbe ati igbimo lati mu oro na ni okunkundun, awon igbese pataki ti a le gbe ni yii:
Oranyan ni fun gbogbo Musulumi lati dide iranlowo si awon omo iya wa nibikibi ti iya ba ti nje won. |
Ekeji: Fifi oro jomitoro oro gbodo ma waye laarin Musulumi ati elesin miran, aladugbo, ore ati ojulumo wipe fifi emi sofo lodi si ilana Olorun Oba, bee sini gbogbo wa pata ni o ye ki a jijo dide lati fi opin sii.
Eketa: Kiko iwe ranse si awon igbimo, egbe ati awon aaye idanileko lati jeki won o mo wipe ise nbe fun awon lati se lori oro awon Musulumi CAR.
Ekerin: Gbogbo awon osise amohunmaworan, oniroyin ati beebelo gbodo wa asiko fun isele yii lati fi han gbogbo aye iru ijiya ti awon oniwa ibaje fi nje awon Musulumi CAR.
Olohun ni onimo julo
::/artbody::
::artendnote:: ::/artendnote::
::artfootnote:: ::/artfootnote::
::artmainimage::oimedia/onislamen/images/mainimages/PipaMusulumi-Re-Ni-Orileede-CAR-Kini-Ojuse-Wa.jpg::/artmainimage::
::artcaption:: ::/artcaption::
::artalt:: ::/artalt::
::artauthor::12811::/artauthor::
::artboximage::::/artboximage::
::artinterviewer:: ::/artinterviewer::
::artcompiler:: ::/artcompiler::
::artreviewer:: ::/artreviewer::
::arttranslator:: ::/arttranslator::
::artsource:: ::/artsource::
::artreference:: ::/artreference::
::artlink1:: ::/artlink1::
::artlinkurl1:: ::/artlinkurl1::
::artlink2:: ::/artlink2::
::artlinkurl2:: ::/artlinkurl2::
::artlink3:: ::/artlink3::
::artlinkurl3:: ::/artlinkurl3::
::artlink4:: ::/artlink4::
::artlinkurl4:: ::/artlinkurl4::
::artlink5:: ::/artlink5::
::artlinkurl5:: ::/artlinkurl5::
::button_submit::::/button_submit::
::jseblodend::::/jseblodend::