Quantcast
Channel: OnIslam Africa
Viewing all articles
Browse latest Browse all 474

Ko Eko Latara Suuru Olohun (Adisi Anabi)

$
0
0

::jseblod::onislam_article::/jseblod::
::onislamarticleaction::::/onislamarticleaction::
::artpretitle:: ::/artpretitle::
::artsubtitle:: ::/artsubtitle::
::artseries:: ::/artseries::
::artlead::Daradara, suuru ati aanu ni o ye ki a ma fi pade gbogbo ibi tabi ibanuje ti o ba nkan wa. Ko leto ki a maa fi oro ya oro, ti a ko ba ni suuru o seese ki iwa ibaje ma po si ni awujo, ti a ko ba ni oju anu yio nira pupo ki alaafia joba laarin ilu.::/artlead::
::artepigraph:: ::/artepigraph::
::artbody:: Abu Musa Al-Ash`ari (Ki Olohunyonu sii) gba Adisi wa lati odo Anabi Muhammad (Ike Olohun ki o ma baa) wipe:

“ Kosi suuru ti a le se afiwe re bi suuri Olohun lori iwa ibaje awon eniyan. Won n so wipe Olohun bi omo sibesibe O tun nfi ike Re bawon lo” Imamu Bukhari ni o gba Adisi yii wa.

Adisi yii nso fun wa bi suuru ati anu Olohun ti to lori awon omo adarihunrun pelu gbogbo iwa aida ti won nfi ojoojumo wu si Olohun Oba Aseda. 

 
   

Read Also:

Omo eniyan gbodo mu ninu suuru Olohun ki o jeki o ma lapa lara re ni gbogbo aye ti ni gbogbo igba

Daradara, suuru ati aanu ni o ye ki a ma fi pade gbogbo ibi tabi ibanuje ti o ba nkan wa.

Ko leto ki a maa fi oro ya oro, ti a ko ba ni suuru o seese ki iwa ibaje ma po si ni awujo, ti a ko ba ni oju anu yio nira pupo ki alaafia joba laarin ilu.

Suuru nio le se okuta jina, suuru ni o jeki a ri idi ododo di mu, suuru ni ko ni jeki a ka abamo lori iwa ti a ba wuu, awon Yoruba sini “Bi Oju ba fi ara bale yio ri imu”.

Gbogbo eyikeyi isele ti o ba sele pelu suuru ni a fi le yanju re, owun ni yio si jeki a gbe are fun alare ati ebi fun elebi.

Siwaju si, Adisi yii nse wa ni oju kokoro wipe ki a maa ni emi idarijin ati emi aanu, kiise gbogbo iwa ibaje ti won ba wu si wa ni a gbodo so wipe a o gba esan re.

Bakana kiise wipe ki a ma se iwadi ibaje tabi ki a dake lori iwa aida kan, orisirisi ona ni Islamu la kale fun wa lati fi opin si iwa ibaje.

Islamu ti se alaye nipa ona abayo nibi eyikeyi iwa aidara ti o ba nsele, a gbodo ma fi oju aanu ba awon eniyan lo yala Musulumi ni tabi elesin miran.

 

Suuru ati aanu ni o ye ki a ma fi pade gbogbo ibi tabi ibanuje ti o ba nkan wa.
Ti won ba wuu iwa ti o ku die kaato si wa  ko leto ki a ni iru iwa aida yii ni a o fi gba esan pada, a ki nfii tipatipa se idajo lowo ara eni, suuru, aanu, aponle ati pelepele ni a fi nyanju gbogbo inkan.

Ti a ba wa ni ipo eniti o wu iwa  aida ki a ri wipe a tete wa atunse si i, ki a ma  se ni taani yio mu mi, Olohun Oba nikan ni won kii bi lere owun ti o ba se.

Ni otito, o nira dire ki eniyan so wipe daadaa ati suuru ni owun yio ma fi ba eniti o nse aida si owun lo, sugbon o ye ki a mo wipe daadaa ni a gbodo ma se ni gbogbo igba, ki a si tun gba wipe tori ti Olohun ni a fi nse, kosi enikankan ti o le san wa ni esan oore ayafi Olohun.

Gbogbo awon ti won iwa owo won ku die kaato yii, eda Olohun ni gbogbo won, ti a aba si nfi suuru at oju aanu bawon lo Olohun Oba Aleke Ola yio ma fi aanu ati ike Re ba awa na lo, nitoripe owun ni Oba Ajoke, Oba Asake Oba ti oore ati aanu Re kari gbogbo aye.

::/artbody::
::artendnote:: ::/artendnote::
::artfootnote:: ::/artfootnote::
::artmainimage::oimedia/onislamen/images/mainimages/KoEkoLatara-Suuru-Olohun-Adisi-Anabi.jpg::/artmainimage::
::artcaption:: ::/artcaption::
::artalt:: ::/artalt::
::artauthor::12811::/artauthor::
::artboximage::::/artboximage::
::artinterviewer:: ::/artinterviewer::
::artcompiler:: ::/artcompiler::
::artreviewer:: ::/artreviewer::
::arttranslator:: ::/arttranslator::
::artsource:: ::/artsource::
::artreference:: ::/artreference::
::artlink1:: ::/artlink1::
::artlinkurl1:: ::/artlinkurl1::
::artlink2:: ::/artlink2::
::artlinkurl2:: ::/artlinkurl2::
::artlink3:: ::/artlink3::
::artlinkurl3:: ::/artlinkurl3::
::artlink4:: ::/artlink4::
::artlinkurl4:: ::/artlinkurl4::
::artlink5:: ::/artlink5::
::artlinkurl5:: ::/artlinkurl5::
::button_submit::::/button_submit::
::jseblodend::::/jseblodend::

Viewing all articles
Browse latest Browse all 474

Trending Articles